1
Iṣe Apo 10:34-35
Bibeli Mimọ
Peteru si yà ẹnu rẹ̀, o si wipe, Nitõtọ mo woye pe, Ọlọrun kì iṣe ojuṣaju enia: Ṣugbọn ni gbogbo orilẹ-ède, ẹniti o ba bẹ̀ru rẹ̀, ti o si nṣiṣẹ ododo, ẹni itẹwọgba ni lọdọ rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 10:34-35
2
Iṣe Apo 10:43
On ni gbogbo awọn woli jẹri si pe, nipa orukọ rẹ̀ li ẹnikẹni ti o ba gbà a gbọ, yio ri imukuro ẹ̀ṣẹ gbà.
Ṣàwárí Iṣe Apo 10:43
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò