1
Iṣe Apo 19:6
Bibeli Mimọ
Nigbati Paulu si gbe ọwọ́ le wọn, Ẹmí Mimọ́ si bà le wọn; nwọn si nfọ̀ ède miran, nwọn si nsọ asọtẹlẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 19:6
2
Iṣe Apo 19:11-12
Ọlọrun si ti ọwọ́ Paulu ṣe iṣẹ aṣẹ akanṣe, Tobẹ̃ ti a fi nmu gèle ati ibantẹ́ ara rẹ̀ tọ̀ awọn olokunrun lọ, arùn si fi wọn silẹ, ati awọn ẹmi buburu si jade kuro lara wọn.
Ṣàwárí Iṣe Apo 19:11-12
3
Iṣe Apo 19:15
Ẹmi buburu na si dahùn, o ni, Jesu emi mọ̀, Paulu emi si mọ̀; ṣugbọn tali ẹnyin?
Ṣàwárí Iṣe Apo 19:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò