1
Iṣe Apo 22:16
Bibeli Mimọ
Njẹ nisisiyi kini iwọ nduro de? Dide, ki a si baptisi rẹ, ki o si wẹ̀ ẹ̀ṣẹ rẹ nù, ki o si mã pè orukọ Oluwa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 22:16
2
Iṣe Apo 22:14
O si wipe, Ọlọrun awọn baba wa yàn ọ, lati mọ̀ ifẹ rẹ̀, ati lati ri Olõtọ nì, ati lati gbọ́ ohùn li ẹnu rẹ̀
Ṣàwárí Iṣe Apo 22:14
3
Iṣe Apo 22:15
Ki iwọ ki o le ṣe ẹlẹri rẹ̀ fun gbogbo enia, li ohun ti iwọ ti ri ti iwọ si ti gbọ́.
Ṣàwárí Iṣe Apo 22:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò