1
Iṣe Apo 27:25
Bibeli Mimọ
Njẹ nitorina, alàgba, ẹ daraya: nitori mo gbà Ọlọrun gbọ́ pe, yio ri bẹ̃ gẹgẹ bi a ti sọ fun mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Iṣe Apo 27:25
2
Iṣe Apo 27:23-24
Nitori angẹli Ọlọrun, ti ẹniti emi iṣe, ati ẹniti emi nsìn, o duro tì mi li oru aná, O wipe, Má bẹ̀ru, Paulu; iwọ kò le ṣaima duro niwaju Kesari: si wo o, Ọlọrun ti fi gbogbo awọn ti o ba ọ wọkọ̀ pọ̀ fun ọ.
Ṣàwárí Iṣe Apo 27:23-24
3
Iṣe Apo 27:22
Njẹ nisisiyi mo gbà nyin niyanju, ki ẹ tújuka: nitori kì yio si òfo ẹmí ninu nyin, bikoṣe ti ọkọ̀.
Ṣàwárí Iṣe Apo 27:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò