1
Kol 4:6
Bibeli Mimọ
Ẹ jẹ ki ọ̀rọ nyin ki o dàpọ mọ́ ore-ọfẹ nigbagbogbo, eyiti a fi iyọ̀ dùn, ki ẹnyin ki o le mọ̀ bi ẹnyin ó ti mã dá olukuluku enia lohùn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Kol 4:6
2
Kol 4:2
Ẹ mã duro ṣinṣin ninu adura igbà, ki ẹ si mã ṣọra ninu rẹ̀ pẹlu idupẹ
Ṣàwárí Kol 4:2
3
Kol 4:5
Ẹ mã rìn nipa ọgbọ́n si awọn ti mbẹ lode, ki ẹ si mã ṣe ìrapada ìgba.
Ṣàwárí Kol 4:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò