1
Deu 32:4
Bibeli Mimọ
Apata na, pipé ni iṣẹ rẹ̀; nitoripe idajọ ni gbogbo ọ̀na rẹ̀: Ọlọrun otitọ ati alàiṣegbe, ododo ati otitọ li on.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deu 32:4
2
Deu 32:39
Wò o nisisiyi pe Emi, ani Emi ni, kò si sí ọlọrun pẹlu mi: mo pa, mo si sọ di ãye; mo ṣalọgbẹ, mo si mu jiná; kò si sí ẹnikan ti o le gbà silẹ li ọwọ́ mi.
Ṣàwárí Deu 32:39
3
Deu 32:3
Nitoriti emi o kokikí orukọ OLUWA kiri: ẹ fi ọlá fun Ọlọrun wa.
Ṣàwárí Deu 32:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò