1
Deu 34:10
Bibeli Mimọ
Wolĩ kan kò si hù mọ́ ni Israeli bi Mose, ẹniti OLUWA mọ̀ li ojukoju
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deu 34:10
2
Deu 34:9
Joṣua ọmọ Nuni si kún fun ẹmi ọgbọ́n; nitoripe Mose ti fi ọwọ́ rẹ̀ lé e lori: awọn ọmọ Israeli si gbà tirẹ̀ gbọ́, nwọn si ṣe bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose.
Ṣàwárí Deu 34:9
3
Deu 34:7
Mose si jẹ́ ẹni ọgọfa ọdún nigbati o kú: oju rẹ̀ kò ṣe baìbai, bẹ̃li agbara rẹ̀ kò dinku.
Ṣàwárí Deu 34:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò