1
Oni 7:9
Bibeli Mimọ
Máṣe yara li ọkàn rẹ lati binu, nitoripe ibinu simi li aiya aṣiwère.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Oni 7:9
2
Oni 7:14
Li ọjọ alafia, mã yọ̀, ṣugbọn li ọjọ ipọnju, ronu pe, bi Ọlọrun ti da ekini bẹ̃li o da ekeji, niti idi eyi pe ki enia ki o máṣe ri nkan ti mbọ̀ lẹhin rẹ̀.
Ṣàwárí Oni 7:14
3
Oni 7:8
Opin nkan san jù ipilẹṣẹ rẹ̀ lọ: ati onisuru ọkàn jù ọlọkàn igberaga.
Ṣàwárí Oni 7:8
4
Oni 7:20
Nitoriti kò si olõtọ enia lori ilẹ, ti nṣe rere ti kò si dẹṣẹ.
Ṣàwárí Oni 7:20
5
Oni 7:12
Nitoripe ãbò li ọgbọ́n, ani bi owo ti jẹ́ abò: ṣugbọn ère ìmọ ni pe, ọgbọ́n fi ìye fun awọn ti o ni i.
Ṣàwárí Oni 7:12
6
Oni 7:1
ORUKỌ rere dara jù ororo ikunra; ati ọjọ ikú jù ọjọ ibi enia lọ.
Ṣàwárí Oni 7:1
7
Oni 7:5
O san lati gbọ́ ibawi ọlọgbọ́n jù ki enia ki o fetisi orin aṣiwère.
Ṣàwárí Oni 7:5
8
Oni 7:2
O dara lati lọ si ile ọ̀fọ jù ati lọ si ile àse: nitoripe eyi li opin gbogbo enia; alãye yio si pa a mọ́ li aiya rẹ̀.
Ṣàwárí Oni 7:2
9
Oni 7:4
Aiya ọlọgbọ́n mbẹ ni ile ọ̀fọ; ṣugbọn aiya aṣiwère ni ile iré.
Ṣàwárí Oni 7:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò