1
Eks 24:17-18
Bibeli Mimọ
Iwò ogo OLUWA dabi iná ajonirun li ori òke na li oju awọn ọmọ Israeli. Mose si lọ sãrin awọsanma na, o sì gùn ori òke na: Mose si wà lori òke li ogoji ọsán ati ogoji oru.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Eks 24:17-18
2
Eks 24:16
Ogo OLUWA si sọkalẹ sori òke Sinai, awọsanma na si bò o mọlẹ ni ijọ́ mẹfa: ni ijọ́ keje o ké si Mose lati ãrin awọsanma wá.
Ṣàwárí Eks 24:16
3
Eks 24:12
OLUWA si wi fun Mose pe, Gòke tọ̀ mi wá sori òke, ki o si duro nibẹ̀; emi o si fi walã okuta fun ọ, ati aṣẹ kan, ati ofin ti mo ti kọ, ki iwọ ki o le ma kọ́ wọn.
Ṣàwárí Eks 24:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò