1
Isa 14:12
Bibeli Mimọ
Bawo ni iwọ ti ṣe ṣubu lati ọrun wá, Iwọ Lusiferi, iràwọ owurọ! bawo li a ti ṣe ke ọ lu ilẹ, iwọ ti o ti ṣẹ́ awọn orilẹ-ède li apa!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isa 14:12
2
Isa 14:13
Nitori iwọ ti wi li ọkàn rẹ pe, Emi o goke lọ si ọrun, emi o gbe itẹ mi ga kọja iràwọ Ọlọrun: emi o si joko lori oke ijọ enia ni iha ariwa
Ṣàwárí Isa 14:13
3
Isa 14:14
Emi o goke kọja giga awọsanma: emi o dabi ọga-ogo jùlọ.
Ṣàwárí Isa 14:14
4
Isa 14:15
Ṣugbọn a o mu ọ sọkalẹ si ipò okú, si iha ihò.
Ṣàwárí Isa 14:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò