1
Isa 26:3
Bibeli Mimọ
Iwọ o pa a mọ li alafia pipé, ọkàn ẹniti o simi le ọ: nitoriti o gbẹkẹle ọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isa 26:3
2
Isa 26:4
Ẹ gbẹkẹle Oluwa titi lai: nitori Oluwa Jehofa li apata aiyeraiye
Ṣàwárí Isa 26:4
3
Isa 26:9
Ọkàn mi li emi fi ṣe afẹ̃ri rẹ li oru; nitõtọ, pẹlu ẹmi mi ninu mi li emi o wá ọ ni kutùkutù; nitori nigbati idajọ rẹ mbẹ ni ilẹ, awọn ti mbẹ li aiye yio kọ́ ododo.
Ṣàwárí Isa 26:9
4
Isa 26:12
Oluwa, iwọ o fi idi alafia mulẹ fun wa: pẹlupẹlu nitori iwọ li o ti ṣe gbogbo iṣẹ wa fun wa.
Ṣàwárí Isa 26:12
5
Isa 26:8
Nitõtọ, Oluwa, li ọ̀na idajọ rẹ, li awa duro de ọ: ifẹ́ ọkàn wa ni si orukọ rẹ, ati si iranti rẹ.
Ṣàwárí Isa 26:8
6
Isa 26:7
Ọ̀na awọn olõtọ ododo ni: iwọ, olõtọ-julọ, ti wọ̀n ipa-ọ̀na awọn olõtọ.
Ṣàwárí Isa 26:7
7
Isa 26:5
Nitori o rẹ̀ awọn ti ngbe oke giga silẹ; ilu giga, o mu u wálẹ; o mu u wálẹ; ani si ilẹ; o mu u de inu ekuru.
Ṣàwárí Isa 26:5
8
Isa 26:2
Ẹ ṣi ilẹkun bodè silẹ, ki orilẹ-ède ododo ti nṣọ́ otitọ ba le wọ̀ ile.
Ṣàwárí Isa 26:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò