1
Isa 5:20
Bibeli Mimọ
Egbe ni fun awọn ti npè ibi ni rere, ati rere ni ibi, ti nfi okùnkun ṣe imọlẹ, ati imọlẹ ṣe okùnkun: ti nfi ikorò pe adùn, ati adùn pe ikorò!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isa 5:20
2
Isa 5:21
Egbe ni fun awọn ti nwọn gbọ́n li oju ara wọn, ti nwọn si mọ̀ oye li oju ara wọn!
Ṣàwárí Isa 5:21
3
Isa 5:13
Nitorina awọn enia mi lọ si oko-ẹrú, nitoriti oye kò si, awọn ọlọla wọn di rirù, ati ọ̀pọlọpọ wọn gbẹ fun orùngbẹ.
Ṣàwárí Isa 5:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò