1
Job 28:28
Bibeli Mimọ
Ati fun enia li o wipe, kiyesi i; Ẹru Oluwa, eyi li ọgbọ́n, ati lati jade kuro ninu ìwa-buburu eyi li oye!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Job 28:28
2
Job 28:12-13
Ṣugbọn nibo li a o gbe wá ọgbọ́n ri, nibo si ni ibi oye? Enia kò mọ̀ iye rẹ̀, bẹ̃li a kò le iri i ni ilẹ awọn alãyè.
Ṣàwárí Job 28:12-13
3
Job 28:20-21
Nibo ha li ọgbọn ti jade wá; tabi nibo ni ibi oye? A ri pe, o lumọ kuro li oju awọn alãyè gbogbo, o si fara sin fun ẹiyẹ oju ọrun.
Ṣàwárí Job 28:20-21
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò