1
Luk 2:11
Bibeli Mimọ
Nitori a bí Olugbala fun nyin loni ni ilu Dafidi, ti iṣe Kristi Oluwa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Luk 2:11
2
Luk 2:10
Angẹli na si wi fun wọn pe, Má bẹ̀ru: sawò o, mo mu ihinrere ayọ̀ nla fun nyin wá, ti yio ṣe ti enia gbogbo.
Ṣàwárí Luk 2:10
3
Luk 2:14
Ogo ni fun Ọlọrun loke ọrun, ati li aiye alafia, ifẹ inu rere si enia.
Ṣàwárí Luk 2:14
4
Luk 2:52
Jesu si npọ̀ li ọgbọ́n, o si ndàgba, o si wà li ojurere li ọdọ Ọlọrun ati enia.
Ṣàwárí Luk 2:52
5
Luk 2:12
Eyi ni yio si ṣe àmi fun nyin; ẹnyin ó ri ọmọ-ọwọ ti a fi ọja wé, o dubulẹ ni ibujẹ ẹran.
Ṣàwárí Luk 2:12
6
Luk 2:8-9
Awọn oluṣọ-agutan mbẹ ni ilu na, nwọn nṣọ agbo agutan wọn li oru ni pápá ti nwọn ngbé. Sá si kiyesi i, angẹli Oluwa na yọ si wọn, ogo Oluwa si ràn yi wọn ká: ẹ̀ru si ba wọn gidigidi.
Ṣàwárí Luk 2:8-9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò