1
Luk 24:49
Bibeli Mimọ
Si kiyesi i, Mo rán ileri Baba mi si nyin: ṣugbọn ẹ joko ni ilu Jerusalemu, titi a o fi fi agbara wọ̀ nyin, lati oke ọrun wá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Luk 24:49
2
Luk 24:6
Ko si nihinyi, ṣugbọn o jinde: ẹ ranti bi o ti wi fun nyin nigbati o wà ni Galili
Ṣàwárí Luk 24:6
3
Luk 24:31-32
Oju wọn si là, nwọn si mọ̀ ọ; o si nù mọ wọn li oju. Nwọn si ba ara wọn sọ pe, Ọkàn wa kò ha gbiná ninu wa, nigbati o mba wa sọ̀rọ li ọna, ati nigbati o ntumọ̀ iwe-mimọ́ fun wa?
Ṣàwárí Luk 24:31-32
4
Luk 24:46-47
O si wi fun wọn pe, Bẹ̃li a ti kọwe rẹ̀, pe, ki Kristi ki o jìya, ati ki o si jinde ni ijọ kẹta kuro ninu okú: Ati ki a wasu ironupiwada ati idariji ẹ̀ṣẹ li orukọ rẹ̀, li orilẹ-ède gbogbo, bẹ̀rẹ lati Jerusalemu lọ.
Ṣàwárí Luk 24:46-47
5
Luk 24:2-3
Nwọn si ba a, a ti yi okuta kuro li ẹnu ibojì. Nigbati nwọn wọ̀ inu rẹ̀, nwọn kò si ri okú Jesu Oluwa.
Ṣàwárí Luk 24:2-3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò