1
Mat 4:4
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn o dahùn wipe, A ti kọwe rẹ̀ pe, Enia kì yio wà lãyè nipa akara nikan, bikoṣe nipa gbogbo ọ̀rọ ti o ti ẹnu Ọlọrun jade wá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Mat 4:4
2
Mat 4:10
Nigbana ni Jesu wi fun u pe, Pada kuro lẹhin mi, Satani: nitori a kọwe rẹ̀ pe, Oluwa Ọlọrun rẹ ni ki iwọ ki o foribalẹ fun, on nikanṣoṣo ni ki iwọ mã sìn.
Ṣàwárí Mat 4:10
3
Mat 4:7
Jesu si wi fun u pe, A tún kọ ọ pe, Iwọ ko gbọdọ dán Oluwa Ọlọrun rẹ wò.
Ṣàwárí Mat 4:7
4
Mat 4:1-2
NIGBANA li a dari Jesu si ijù lati ọwọ́ Ẹmi lati dán a wò lọwọ Èṣu. Nigbati o si ti gbàwẹ li ogoji ọsán ati ogoji oru, lẹhinna ni ebi npa a.
Ṣàwárí Mat 4:1-2
5
Mat 4:19-20
O si wi fun wọn pe, Ẹ mã tọ̀ mi lẹhin, emi ó si sọ nyin di apẹja enia. Nwọn si fi àwọn silẹ lojukanna, nwọn sì tọ̀ ọ lẹhin.
Ṣàwárí Mat 4:19-20
6
Mat 4:17
Lati igbana ni Jesu bẹ̀rẹ si iwasu wipe, Ẹ ronupiwada; nitori ijọba ọrun kù si dẹ̀dẹ.
Ṣàwárí Mat 4:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò