1
Nah 3:1
Bibeli Mimọ
EGBE ni fun ilu ẹjẹ̀ nì! gbogbo rẹ̀ kun fun eké, ati olè, ijẹ kò kuro
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Nah 3:1
2
Nah 3:19
Kò si ipajumọ fun ifarapa rẹ; ọgbẹ rẹ kún fun irora, gbogbo ẹniti o gbọ́ ihin rẹ yio pàtẹwọ le ọ lori, nitori li ori tani ìwa-buburu rẹ kò ti kọja nigbagbogbo?
Ṣàwárí Nah 3:19
3
Nah 3:7
Yio si ṣe pe, gbogbo awọn ti o wò ọ yio sa fun ọ, nwọn o si wipe, A ti fi Ninefe ṣòfo: tani yio kẹdùn rẹ̀? nibo ni emi o ti wá olutùnu fun ọ?
Ṣàwárí Nah 3:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò