1
File 1:6
Bibeli Mimọ
Ki idapọ igbagbọ́ rẹ le lagbara, ni imọ ohun rere gbogbo ti mbẹ ninu nyin si Kristi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí File 1:6
2
File 1:7
Emi sá ni ayọ̀ pupọ ati itunu nitori ifẹ rẹ, nitoriti a tù ọkàn awọn enia mimọ́ lara lati ọwọ́ rẹ wá, arakunrin.
Ṣàwárí File 1:7
3
File 1:4
Emi ndupẹ lọwọ Ọlọrun mi nigbagbogbo, emi nṣe iranti rẹ ninu adura mi
Ṣàwárí File 1:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò