1
Owe 19:21
Bibeli Mimọ
Ete pupọ li o wà li aiya enia; ṣugbọn ìgbimọ Oluwa, eyini ni yio duro.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 19:21
2
Owe 19:17
Ẹniti o ṣãnu fun talaka Oluwa li o win; ati iṣeun rẹ̀, yio san a pada fun u.
Ṣàwárí Owe 19:17
3
Owe 19:11
Imoye enia mu u lọra ati binu; ogo rẹ̀ si ni lati ré ẹ̀ṣẹ kọja.
Ṣàwárí Owe 19:11
4
Owe 19:20
Fetisi ìmọ ki o si gbà ẹkọ́, ki iwọ ki o le gbọ́n ni igbẹhin rẹ.
Ṣàwárí Owe 19:20
5
Owe 19:23
Ibẹ̀ru Oluwa tẹ̀ si ìye: ẹniti o ni i yio joko ni itẹlọrun; a kì yio fi ibi bẹ̀ ẹ wọ́.
Ṣàwárí Owe 19:23
6
Owe 19:8
Ẹniti o gbọ́n, o fẹ ọkàn ara rẹ̀: ẹniti o pa oye mọ́ yio ri rere.
Ṣàwárí Owe 19:8
7
Owe 19:18
Nà ọmọ rẹ nigbati ireti wà, má si ṣe gbe ọkàn rẹ le ati pa a.
Ṣàwárí Owe 19:18
8
Owe 19:9
Ẹlẹri eke kì yio lọ laijiya, ẹniti o si nṣeke yio ṣegbe.
Ṣàwárí Owe 19:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò