1
Owe 25:28
Bibeli Mimọ
Ẹniti kò le ṣe akoso ara rẹ̀, o dabi ilu ti a wo lulẹ, ti kò si li odi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 25:28
2
Owe 25:21-22
Bi ebi ba npa ọta rẹ, fun u li onjẹ; bi ongbẹ ba si gbẹ ẹ, fun u li ohun mimu. Nitoriti iwọ o kó ẹyin iná jọ si ori rẹ̀, Oluwa yio san fun ọ.
Ṣàwárí Owe 25:21-22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò