1
Owe 27:17
Bibeli Mimọ
Irin a ma pọn irin: bẹ̃li ọkunrin ipọn oju ọrẹ́ rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 27:17
2
Owe 27:1
MÁṢE leri ara rẹ niti ọjọ ọla, nitoriti iwọ kò mọ̀ ohun ti ọjọ kan yio hù jade.
Ṣàwárí Owe 27:1
3
Owe 27:6
Otitọ li ọgbẹ ọrẹ́: ṣugbọn ifẹnukonu ọta li ẹ̀tan.
Ṣàwárí Owe 27:6
4
Owe 27:19
Bi oju ti ikò oju li omi, bẹ̃li aiya enia si enia.
Ṣàwárí Owe 27:19
5
Owe 27:2
Jẹ ki ẹlomiran ki o yìn ọ, ki o máṣe ẹnu ara rẹ; alejo, ki o má si ṣe ète ara rẹ.
Ṣàwárí Owe 27:2
6
Owe 27:5
Ibawi nigbangba, o san jù ifẹ ti o farasin lọ.
Ṣàwárí Owe 27:5
7
Owe 27:15
Ọṣọrọ-òjo li ọjọ òjo, ati onija obinrin, bakanna ni.
Ṣàwárí Owe 27:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò