1
O. Daf 113:3
Bibeli Mimọ
Lati ila-õrun titi o fi de ìwọ rẹ̀ orukọ Oluwa ni ki a yìn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 113:3
2
O. Daf 113:9
O mu àgan obinrin gbe inu ile, lati ma ṣe oninu-didùn iya awọn ọmọ. Ẹ ma yìn Oluwa!
Ṣàwárí O. Daf 113:9
3
O. Daf 113:7
O gbé talaka soke lati inu erupẹ wá, o si gbé olupọnju soke lati ori àtan wá
Ṣàwárí O. Daf 113:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò