1
O. Daf 26:2-3
Bibeli Mimọ
Wadi mi, Oluwa, ki o si ridi mi; dán inu mi ati ọkàn mi wò. Nitoriti iṣeun-ifẹ rẹ mbẹ niwaju mi: emi si ti nrìn ninu otitọ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 26:2-3
2
O. Daf 26:1
ṢE idajọ mi, Oluwa; nitori ti mo ti nrìn ninu ìwa titọ mi; emi ti gbẹkẹle Oluwa pẹlu; njẹ ẹsẹ mi kì yio yẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 26:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò