1
O. Daf 34:18
Bibeli Mimọ
Oluwa mbẹ leti ọdọ awọn ti iṣe onirobinujẹ ọkàn; o si gbà iru awọn ti iṣe onirora ọkàn là.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 34:18
2
O. Daf 34:4
Emi ṣe afẹri Oluwa, o si gbohùn mi; o si gbà mi kuro ninu gbogbo ìbẹru mi.
Ṣàwárí O. Daf 34:4
3
O. Daf 34:19
Ọ̀pọlọpọ ni ipọnju olododo; ṣugbọn Oluwa gbà a ninu wọn gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 34:19
4
O. Daf 34:8
Tọ́ ọ wò, ki o si ri pe, rere ni Oluwa: alabukún fun li ọkunrin na ti o gbẹkẹle e.
Ṣàwárí O. Daf 34:8
5
O. Daf 34:5
Nwọn wò o, imọlẹ si mọ́ wọn: oju kò si tì wọn.
Ṣàwárí O. Daf 34:5
6
O. Daf 34:17
Awọn olododo nke, Oluwa si gbọ́, o si yọ wọn jade ninu iṣẹ́ wọn gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 34:17
7
O. Daf 34:7
Angeli Oluwa yi awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀ ká, o si gbà wọn.
Ṣàwárí O. Daf 34:7
8
O. Daf 34:14
Lọ kuro ninu ibi, ki o si ma ṣe rere; ma wá alafia, ki o si lepa rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 34:14
9
O. Daf 34:13
Pa ahọn rẹ mọ́ kuro ninu ibi, ati ète rẹ kuro li ẹ̀tan sisọ.
Ṣàwárí O. Daf 34:13
10
O. Daf 34:15
Oju Oluwa mbẹ lara awọn olododo, eti rẹ̀ si ṣi si igbe wọn.
Ṣàwárí O. Daf 34:15
11
O. Daf 34:3
Gbé Oluwa ga pẹlu mi, ki a si jumọ gbé orukọ rẹ̀ leke.
Ṣàwárí O. Daf 34:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò