1
O. Daf 45:7
Bibeli Mimọ
Iwọ fẹ ododo, iwọ korira ìwa-buburu: nitori na li Ọlọrun, Ọlọrun rẹ, ṣe fi àmi ororo ayọ̀ yà ọ ṣolori awọn ọ̀gba rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 45:7
2
O. Daf 45:6
Ọlọrun, lai ati lailai ni itẹ́ rẹ: ọpá-alade ijọba rẹ, ọpá-alade otitọ ni.
Ṣàwárí O. Daf 45:6
3
O. Daf 45:17
Emi o ma ṣe orukọ rẹ ni iranti ni iran gbogbo: nitorina li awọn enia yio ṣe ma yìn ọ lai ati lailai.
Ṣàwárí O. Daf 45:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò