1
O. Daf 58:11
Bibeli Mimọ
Bẹ̃li enia o si wipe, Lõtọ, ère mbẹ fun olododo: lõtọ, on li Ọlọrun ti o nṣe idajọ ni aiye.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 58:11
2
O. Daf 58:3
Lati inu iya wọn wá li awọn enia buburu ti ṣe iyapa: nwọn ti ṣina lojukanna ti a ti bi wọn, nwọn a ma ṣeke.
Ṣàwárí O. Daf 58:3
3
O. Daf 58:1-2
ẸNYIN ha nsọ ododo nitõtọ, ẹnyin ijọ enia? ẹnyin ha nṣe idajọ ti o ṣe titọ, ẹnyin ọmọ enia? Nitõtọ, ẹnyin nṣiṣẹ buburu li aiya; ẹnyin nwọ̀n ìwa-agbara ọwọ nyin li aiye.
Ṣàwárí O. Daf 58:1-2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò