1
O. Daf 81:10
Bibeli Mimọ
Emi ni Oluwa Ọlọrun rẹ, ti o mu ọ lati ilẹ Egipti jade wá: yà ẹ̀nu rẹ̀ gbòro, emi o si kún u.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 81:10
2
O. Daf 81:13-14
Ibaṣepe awọn enia mi ti gbọ́ ti emi, ati ki Israeli ki o ma rìn nipa ọ̀na mi! Emi iba ti ṣẹ́ awọn ọta wọn lọgan, emi iba si ti yi ọwọ mi pada si awọn ọta wọn.
Ṣàwárí O. Daf 81:13-14
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò