1
O. Daf 83:18
Bibeli Mimọ
Ki awọn enia ki o le mọ̀ pe iwọ, orukọ ẹni-kanṣoṣo ti ijẹ Jehofah, iwọ li Ọga-ogo lori aiye gbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 83:18
2
O. Daf 83:1
MAṢE dakẹ, Ọlọrun: máṣe pa ẹnu rẹ mọ́, ki o má si ṣe duro jẹ, Ọlọrun.
Ṣàwárí O. Daf 83:1
3
O. Daf 83:16
Fi ìtiju kún wọn li oju: ki nwọn o le ma ṣe afẹri orukọ rẹ, Oluwa.
Ṣàwárí O. Daf 83:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò