1
O. Daf 94:19
Bibeli Mimọ
Ninu ọ̀pọlọpọ ibinujẹ mi ninu mi, itunu rẹ li o nmu inu mi dùn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 94:19
2
O. Daf 94:18
Nigbati mo wipe, Ẹsẹ mi yọ́; Oluwa, ãnu rẹ dì mi mu.
Ṣàwárí O. Daf 94:18
3
O. Daf 94:22
Ṣugbọn Oluwa li àbo mi; Ọlọrun mi si li apata àbo mi
Ṣàwárí O. Daf 94:22
4
O. Daf 94:12
Ibukún ni fun enia na ẹniti iwọ nà, Oluwa, ti iwọ si kọ́ lati inu ofin rẹ wá
Ṣàwárí O. Daf 94:12
5
O. Daf 94:17
Bikoṣe bi Oluwa ti ṣe oluranlọwọ mi; ọkàn mi fẹrẹ joko ni idakẹ.
Ṣàwárí O. Daf 94:17
6
O. Daf 94:14
Nitoripe Oluwa kì yio ṣa awọn enia rẹ̀ tì, bẹ̃ni kì yio kọ̀ awọn enia-ini rẹ̀ silẹ.
Ṣàwárí O. Daf 94:14
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò