1
O. Daf 96:4
Bibeli Mimọ
Nitori ti Oluwa tobi, o si ni iyìn pupọ̀pupọ̀: on li o ni ìbẹru jù gbogbo oriṣa lọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 96:4
2
O. Daf 96:2
Ẹ kọrin si Oluwa, fi ibukún fun orukọ rẹ̀; ẹ ma fi igbala rẹ̀ hàn lati ọjọ de ọjọ.
Ṣàwárí O. Daf 96:2
3
O. Daf 96:1
Ẹ kọrin titun si Oluwa: ẹ kọrin si Oluwa gbogbo aiye.
Ṣàwárí O. Daf 96:1
4
O. Daf 96:3
Sọ̀rọ ogo rẹ̀ lãrin awọn keferi, ati iṣẹ iyanu rẹ̀ lãrin gbogbo enia.
Ṣàwárí O. Daf 96:3
5
O. Daf 96:9
Ẹ ma sìn Oluwa ninu ẹwà ìwa-mimọ́: ẹ wariri niwaju rẹ̀, gbogbo aiye.
Ṣàwárí O. Daf 96:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò