1
O. Daf 98:1
Bibeli Mimọ
Ẹ kọrin titun si Oluwa; nitoriti o ti ṣe ohun iyanu: ọwọ ọtún rẹ̀, ati apa rẹ̀ mimọ́ li o ti mu igbala wa fun ara rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 98:1
2
O. Daf 98:4
Ẹ ho iho ayọ̀ si Oluwa, gbogbo aiye: ẹ ho yè, ẹ yọ̀, ki ẹ si ma kọrin iyìn.
Ṣàwárí O. Daf 98:4
3
O. Daf 98:9
Niwaju Oluwa; nitori ti mbọwa iṣe idajọ aiye: pẹlu ododo ni yio fi ṣe idajọ aiye, ati awọn orilẹ-ède li aiṣègbe.
Ṣàwárí O. Daf 98:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò