1
Rom 10:9
Bibeli Mimọ
Pe, bi iwọ ba fi ẹnu rẹ jẹwọ Jesu li Oluwa, ti iwọ si gbagbọ́ li ọkàn rẹ pe, Ọlọrun jí i dide kuro ninu okú, a o gbà ọ là.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Rom 10:9
2
Rom 10:10
Nitori ọkàn li a fi igbagbọ́ si ododo; ẹnu li a si fi ijẹwọ si igbala.
Ṣàwárí Rom 10:10
3
Rom 10:17
Njẹ nipa gbigbọ ni igbagbọ́ ti iwá, ati gbigbọ nipa ọ̀rọ Ọlọrun.
Ṣàwárí Rom 10:17
4
Rom 10:11-13
Nitori iwe-mimọ́ wipe, Ẹnikẹni ti o ba gbà a gbọ́ oju ki yio ti i. Nitori kò si ìyatọ ninu Ju ati Hellene: nitori Oluwa kanna l'Oluwa gbogbo wọn, o si pọ̀ li ọrọ̀ fun gbogbo awọn ti nkepè e. Nitori ẹnikẹni ti o ba sá pè orukọ, Oluwa, li a o gbàlà.
Ṣàwárí Rom 10:11-13
5
Rom 10:15
Nwọn o ha si ti ṣe wasu, bikoṣepe a rán wọn? gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe, Ẹsẹ awọn ti nwasu ihinrere alafia ti dara to, awọn ti nwãsu ihin ayọ̀ ohun rere!
Ṣàwárí Rom 10:15
6
Rom 10:14
Njẹ nwọn o ha ti ṣe kepe ẹniti nwọn kò gbagbọ́? nwọn o ha si ti ṣe gbà ẹniti nwọn kò gburó rẹ̀ rí gbọ́? nwọn o ha si ti ṣe gbọ́ laisi oniwasu?
Ṣàwárí Rom 10:14
7
Rom 10:4
Nitori Kristi li opin ofin si ododo fun olukuluku ẹniti o gbagbọ́.
Ṣàwárí Rom 10:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò