1
O. Sol 3:1
Bibeli Mimọ
LI oru lori akete mi, mo wá ẹniti ọkàn mi fẹ: emi wá a, ṣugbọn emi kò ri i.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Sol 3:1
2
O. Sol 3:2
Emi o dide nisisiyi, emi o si rìn lọ ni ilu, ni igboro, ati li ọ̀na gbòro ni emi o wá ẹniti ọkàn mi fẹ: emi wá a, ṣugbọn emi kò ri i.
Ṣàwárí O. Sol 3:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò