1
2 Kọrinti 11:14-15
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kì í sì í ṣe ohun ìyanu; nítorí Satani, tìkára rẹ̀ ń pa ara rẹ̀ dàbí angẹli ìmọ́lẹ̀. Nítorí náà kì í ṣe ohun ńlá bí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú bá pa ara wọn dàbí àwọn ìránṣẹ́ òdodo; ìgbẹ̀yìn àwọn ẹni tí yóò rí gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Kọrinti 11:14-15
2
2 Kọrinti 11:3
Ṣùgbọ́n ẹ̀rù ń bà mí, kí ó má bà á jẹ́ pé, bí ejò ti tan Efa jẹ́ nípasẹ̀ àrékérekè rẹ̀, a lè mú ọkàn yín ṣáko lọ kúrò nínú òtítọ́ yín àti ìfarajì fún Kristi.
Ṣàwárí 2 Kọrinti 11:3
3
2 Kọrinti 11:30
Bí èmi yóò bá ṣògo, èmi ó kúkú máa ṣògo nípa àwọn nǹkan tí ó jẹ́ ti àìlera mi.
Ṣàwárí 2 Kọrinti 11:30
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò