1
2 Kọrinti 8:9
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí ẹ̀yin mọ oore-ọ̀fẹ́ Olúwa wa Jesu Kristi, pé bí òun ti jẹ́ ọlọ́rọ̀ rí ṣùgbọ́n nítorí yín ó di tálákà kí a lè sọ yín di ọlọ́rọ̀ nípa àìní rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Kọrinti 8:9
2
2 Kọrinti 8:2
Bí ó ti jẹ́ pé a dán wọn wò nípa ìpọ́njú, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ayọ̀ àti àìlódiwọ̀n àìní wọn ti kún àkúnwọ́sílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ ìlawọ́ wọn.
Ṣàwárí 2 Kọrinti 8:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò