1
2 Johanu 1:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èyí sì ni ìfẹ́, pé, kí àwa máa rin nípa òfin rẹ̀, èyí ni òfin náà, àní bí ẹ ti gbọ́ ni àtètèkọ́ṣe, pé, kí ẹ̀yin rìn nínú rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Johanu 1:6
2
2 Johanu 1:9
Olúkúlùkù ẹni tí ó bá ń rú òfin tí kò si dúró nínú ẹ̀kọ́ Kristi, kò mọ Ọlọ́run. Ẹni tí ó bá dúró nínú ẹ̀kọ́, òun ni ó mọ Baba àti Ọmọ.
Ṣàwárí 2 Johanu 1:9
3
2 Johanu 1:8
Ẹ kíyèsára yín, kí ẹ má ba à sọ iṣẹ́ tí ẹ tí ṣe nù, ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin lè rí èrè kíkún gbà.
Ṣàwárí 2 Johanu 1:8
4
2 Johanu 1:7
Nítorí ẹlẹ́tàn púpọ̀ ti jáde wa sínú ayé, àwọn tí kò jẹ́wọ́ pé Jesu Kristi wá nínú ara. Èyí ni ẹlẹ́tàn àti aṣòdì sí Kristi.
Ṣàwárí 2 Johanu 1:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò