1
2 Samuẹli 5:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Dafidi sì jẹ́ ẹni ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó jẹ ọba; ó sì jẹ ọba ní ogójì ọdún.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Samuẹli 5:4
2
2 Samuẹli 5:19
Dafidi sì béèrè lọ́dọ̀ OLúWA pé, “Kí èmi ó gòkè tọ àwọn Filistini bí? Ìwọ ó fi wọ́n lé mi lọ́wọ́ bí?” OLúWA sì wí fún Dafidi pé, “Gòkè lọ, nítorí pé dájúdájú èmi ó fi àwọn Filistini lé ọ lọ́wọ́.”
Ṣàwárí 2 Samuẹli 5:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò