1
2 Timotiu 2:15
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣaápọn láti fi ara rẹ̀ hàn níwájú Ọlọ́run bi ẹni tí ó yege àti òṣìṣẹ́ tí kò ní láti tijú, tí ó ń pín ọ̀rọ̀ òtítọ́ bí ó ti yẹ
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Timotiu 2:15
2
2 Timotiu 2:22
Máa sá fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ èwe: sì máa lépa òdodo, ìgbàgbọ́, ìfẹ́, àlàáfíà, pẹ̀lú àwọn tí ń ké pe Olúwa láti inú ọkàn funfun wá.
Ṣàwárí 2 Timotiu 2:22
3
2 Timotiu 2:24
Ìránṣẹ́, Olúwa kò sì gbọdọ̀ jà; bí kò ṣe kí ó jẹ́ ẹni pẹ̀lẹ́ sí ènìyàn gbogbo ẹni tí ó lè kọ́ni, àti onísùúrù.
Ṣàwárí 2 Timotiu 2:24
4
2 Timotiu 2:13
Bí àwa kò bá gbàgbọ́, òun dúró ni olóòtítọ́: Nítorí òun kò lè sẹ́ ara rẹ̀.
Ṣàwárí 2 Timotiu 2:13
5
2 Timotiu 2:25
Ẹni tí yóò máa kọ́ àwọn alátakò pẹ̀lú ìwà tútù, ní ìrètí pé Ọlọ́run lè fún wọn ní ìrònúpìwàdà sí ìmọ̀ òtítọ́
Ṣàwárí 2 Timotiu 2:25
6
2 Timotiu 2:16
Yà kúrò nínú ọ̀rọ̀ asán, nítorí tiwọn máa síwájú nínú àìwà-bí-Ọlọ́run.
Ṣàwárí 2 Timotiu 2:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò