1
Ìṣe àwọn Aposteli 22:16
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ǹjẹ́ nísinsin yìí, kín ni ìwọ ń dúró dè? Dìde, kí a sì bamitiisi rẹ̀, kí ó sì wẹ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ nù, kí ó sì máa pe orúkọ rẹ̀.’
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 22:16
2
Ìṣe àwọn Aposteli 22:14
“Nígbà náà ni ó wí pé: ‘Ọlọ́run àwọn baba wa ti yàn ọ́ láti mọ ìfẹ́ rẹ̀, àti láti ri Ẹni Òdodo náà, àti láti gbọ́ ọ̀rọ̀ láti ẹnu rẹ̀.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 22:14
3
Ìṣe àwọn Aposteli 22:15
Ìwọ yóò jẹ́ ẹlẹ́rìí rẹ̀ fún gbogbo ènìyàn, nínú ohun tí ìwọ tí rí tí ìwọ sì ti gbọ́.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 22:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò