1
Ìṣe àwọn Aposteli 6:3-4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí náà, ará, ẹ wo ọkùnrin méje nínú yín, olórúkọ rere, tí ó kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ àti fún ọgbọ́n, tí àwa lè yàn sí iṣẹ́ yìí. Ṣùgbọ́n àwa yóò dúró ṣinṣin nínú àdúrà gbígbà, àti nínú iṣẹ́ ìránṣẹ́ ọ̀rọ̀ náà.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 6:3-4
2
Ìṣe àwọn Aposteli 6:7
Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sì gbilẹ̀, iye àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì pọ̀ sí i gidigidi ni Jerusalẹmu, ọ̀pọ̀ nínú ẹgbẹ́ àwọn àlùfáà sí fetí sí tí ìgbàgbọ́ náà.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 6:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò