1
Deuteronomi 20:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí OLúWA Ọlọ́run yín ní bá yín lọ, láti bá àwọn ọ̀tá yín jà fún yín, láti gbà yín là.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deuteronomi 20:4
2
Deuteronomi 20:1
Nígbà tí o bá lọ sí ogun pẹ̀lú ọ̀tá rẹ, tí o sì rí ẹṣin àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun àti ológun tí ó jù ọ́ lọ, má ṣe bẹ̀rù u wọn, nítorí OLúWA Ọlọ́run rẹ tí ń mú ọ jáde wá láti ilẹ̀ Ejibiti, yóò wà pẹ̀lú rẹ.
Ṣàwárí Deuteronomi 20:1
3
Deuteronomi 20:3
yóò sì wí pé, “Gbọ́, ìwọ Israẹli, lónìí ò ń jáde lọ sójú ogun sí ọ̀tá rẹ. Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín ṣojo tàbí bẹ̀rù; ẹ má ṣe jáyà tàbí kí ẹ fi ààyè fún ìjayà níwájú u wọn.
Ṣàwárí Deuteronomi 20:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò