1
Deuteronomi 23:23
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Rí i dájú pé o ṣe ohunkóhun tí o bá ti ètè rẹ jáde, nítorí pé ìwọ fi tinútinú rẹ jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLúWA Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú ẹnu ara rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deuteronomi 23:23
2
Deuteronomi 23:21
Bí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLúWA Ọlọ́run rẹ, má ṣe lọ́ra láti san án, nítorí OLúWA Ọlọ́run rẹ yóò béèrè rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ, o sì máa jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀.
Ṣàwárí Deuteronomi 23:21
3
Deuteronomi 23:22
Ṣùgbọ́n tí o bá fàsẹ́yìn láti jẹ́ ẹ̀jẹ́, o kò ní jẹ̀bi.
Ṣàwárí Deuteronomi 23:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò