1
Gẹnẹsisi 30:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà náà ni Ọlọ́run rántí Rakeli, Ọlọ́run sì gbọ́ tirẹ̀, ó sì ṣí i ní inú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 30:22
2
Gẹnẹsisi 30:24
Ó sì pe orúkọ rẹ̀ ni Josẹfu, ó sì wí pé, “Ǹjẹ́ kí OLúWA kí ó fi ọmọkùnrin mìíràn kún un fún mi.”
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 30:24
3
Gẹnẹsisi 30:23
Ó lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan ó sì wí pé, “Ọlọ́run ti mú ẹ̀gàn mi kúrò.”
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 30:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò