1
Gẹnẹsisi 40:8
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Wọ́n wí pé, “Àwa méjèèjì ni a lá àlá, kò sì sí ẹni tí yóò túmọ̀ rẹ̀.” Josẹfu sì wí fún wọn pé, “Ọlọ́run nìkan ni ó ni ìtumọ̀. Ẹ sọ àwọn àlá yín fún mi.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 40:8
2
Gẹnẹsisi 40:23
Ṣùgbọ́n, olórí agbọ́tí kò rántí Josẹfu mọ́, kò tilẹ̀ ronú nípa rẹ̀.
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 40:23
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò