1
Gẹnẹsisi 46:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọlọ́run sì wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run, Ọlọ́run baba rẹ, má ṣe bẹ̀rù láti sọ̀kalẹ̀ lọ sí ilẹ̀ Ejibiti nítorí, èmi yóò sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá níbẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 46:3
2
Gẹnẹsisi 46:4
Èmi yóò sì sọ̀kalẹ̀ pẹ̀lú rẹ lọ sí Ejibiti, èmi yóò sì tún mú ọ padà wá. Ọwọ́ Josẹfu fúnrarẹ̀ ni ìwọ yóò sì kú sí.”
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 46:4
3
Gẹnẹsisi 46:29
Josẹfu tọ́jú kẹ̀kẹ́-ẹṣin rẹ̀ ó sì lọ sí Goṣeni láti pàdé Israẹli baba rẹ̀. Bí Josẹfu ti dé iwájú baba rẹ̀, ó dì mọ́ baba rẹ̀ ó sì sọkún fún ìgbà pípẹ́.
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 46:29
4
Gẹnẹsisi 46:30
Israẹli wí fún Josẹfu pé, “Wàyí o, mo le kú, níwọ̀n bí mo ti rí i fún ara mi pé, o wà láààyè síbẹ̀.”
Ṣàwárí Gẹnẹsisi 46:30
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò