1
Hosea 1:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà tí OLúWA bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ̀rọ̀ láti ẹnu Hosea, OLúWA wí fún un pé, “Lọ, fẹ́ àgbèrè obìnrin kan fún ara rẹ, kí ó sì bí ọmọ àgbèrè fún ọ nípasẹ̀ àwọn ọkùnrin mìíràn, nítorí ilẹ̀ ti ṣẹ ẹ̀ṣẹ̀ àgbèrè púpọ̀ nípa yíyapa kúrò lọ́dọ̀ OLúWA.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Hosea 1:2
2
Hosea 1:7
Síbẹ̀, èmi yóò ṣàánú fún ilé Juda, èmi ó gbà wọ́n—kì í ṣe nípa ọfà, idà tàbí ogun, ẹṣin tàbí kẹ̀kẹ́ ẹlẹ́ṣin bí kò ṣe nípa OLúWA Ọlọ́run wọn.”
Ṣàwárí Hosea 1:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Videos