1
Hosea 4:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Àwọn ènìyàn mi ń ṣègbé nítorí pé wọn kò ní ìmọ̀. “Nítorí pé ẹ ti kọ ìmọ̀ sílẹ̀. Èmi náà kọ̀ yín ní àlùfáà mi; nítorí pé ẹ ti kọ òfin Ọlọ́run yín sílẹ̀ Èmi náà yóò gbàgbé àwọn ọmọ yín.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Hosea 4:6
2
Hosea 4:1
Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ OLúWA ẹ̀yin ọmọ Israẹli, nítorí pé OLúWA fi ẹ̀sùn kan ẹ̀yin tí ń gbé ní ilẹ̀ náà. “Kò sí ìwà òtítọ́, kò sí ìfẹ́ Kò sí ìmọ̀ Ọlọ́run ní ilẹ̀ náà
Ṣàwárí Hosea 4:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Videos