1
Isaiah 14:12
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Báwo ni ìwọ ṣe ṣubú lulẹ̀ láti ọ̀run wá, ìwọ ìràwọ̀ òwúrọ̀, ọmọ òwúrọ̀ náà! A ti sọ ọ́ sílẹ̀ sínú ayé Ìwọ tí o ti tẹ orí àwọn orílẹ̀-èdè ba rí!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 14:12
2
Isaiah 14:13
Ìwọ sọ nínú ọkàn rẹ pé, “Èmi yóò gòkè lọ sí ọ̀run; Èmi yóò gbé ìtẹ́ mi sókè ga ju àwọn ìràwọ̀ Ọlọ́run, Èmi yóò gúnwà ní orí òkè àpéjọ ní ṣóńṣó orí òkè mímọ́.
Ṣàwárí Isaiah 14:13
3
Isaiah 14:14
Èmi yóò gòkè lọ rékọjá àwọn àwọsánmọ̀; Èmi yóò ṣe ara mi gẹ́gẹ́ bí Ọ̀gá-ògo.”
Ṣàwárí Isaiah 14:14
4
Isaiah 14:15
Ṣùgbọ́n a ti rẹ̀ ọ́ sílẹ̀ wọ inú ibojì lọ lọ sí ìsàlẹ̀ ọ̀gbun.
Ṣàwárí Isaiah 14:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò