1
Isaiah 4:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Lẹ́yìn náà, OLúWA yóò dá sórí òkè Sioni àti sórí i gbogbo àwọn tí ó péjọpọ̀ síbẹ̀, kurukuru èéfín ní ọ̀sán àti ìtànṣán ọ̀wọ́-iná ní òru, lórí gbogbo ògo yìí ni ààbò yóò wà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 4:5
2
Isaiah 4:2
Ní ọjọ́ náà, ẹ̀ka OLúWA yóò ní ẹwà àti ògo, èso ilẹ̀ náà yóò sì jẹ́ ìgbéraga àti ògo àwọn ti ó sálà ní Israẹli.
Ṣàwárí Isaiah 4:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò