1
Isaiah 7:14
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí náà, Olúwa fúnra ara rẹ̀ ni yóò fún ọ ní ààmì kan. Wúńdíá kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Emmanueli.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 7:14
2
Isaiah 7:9
Orí Efraimu sì ni Samaria, orí Samaria sì ni ọmọ Remaliah. Bí ẹ̀yin kí yóò bá gbàgbọ́, lóòtítọ́, a kì yóò fi ìdí yín múlẹ̀.’ ”
Ṣàwárí Isaiah 7:9
3
Isaiah 7:15
Òun yóò jẹ wàrà àti oyin nígbà tí ó bá ní ìmọ̀ tó láti kọ ẹ̀bi àti láti yan rere.
Ṣàwárí Isaiah 7:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò